Sellbeta Online Marketplace
778 Reads
File Added: March 31, 2018
Lyrics Added: March 31, 2018
LYRICS:  Brymo  - Olanrewaju Art
Title:
Brymo - Olanrewaju
Added By:
Artiste:
Album:
Uploaded:
March 31, 2018

Read Lyrics:

Lyrics of Brymo - Olanrewaju by Brymo

Igba o lọ bi orere
Bo ba koro oṣi maa dun ah
Eni to ni suuru kii ṣeyan kekere
Bo ba kan lẹ, oṣi maa goke ah
Boo ba ṣe un tọ fe, won maa kẹyin si e (ẹh a ẹh)
Bo ba ṣe tirẹ o, o ma jẹ ire fun ẹ
Ọlanrewaju ọmọ ọba,
E ma suure da gba won ni ko o ṣe were, roora ṣe
E ma suure da gba oo
Olooto ko ni ku si bi ọtẹ ooo
Olanrewaju ọmọ mi, e ma suure da gba oo
Igba o lọ bi orere
Bọmọde oku oo, oṣi maa da gba
Ṣọra funja, ṣọ ra fẹgbẹkẹgbẹ
Oun tio to o, oṣi maa pọ da nu
Gbogbo eni abi lo ma ku
Iwa ta a wu lo ma ku
Ọlanrewaju ọmọ oba, e ma suure da gba o
Won ni ko ṣe were, roora ṣe
E ma suure da gba oo
Olooto ko ni ku sibi ọtẹ oo
Ọlanrewaju ọmọ mi, e ma suure da gba o
Olooto ko ni ku sipo ika oo
Olooto ko ni ku sibi ote oo
Ọlanrewaju ọmọ ọba, ee ma suure dagba oo
Ọlanrewaju ọmọ mi, ee ma suure da gba oo